Pular para o conteúdo
Publicidade

Marcos 6

35 Nígbà ọjọ́ ti lọ tán, àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ tọ̀ ́ , wọ́n fún un , ibi aṣálẹ̀ ni ìbí yìí, ọjọ́ lọ tán. 36 "Rán àwọn ènìyàn wọ̀nyí láti lọ àwọn abúlé àti ìlú láti ra oúnjẹ fún ara wọn."

37 6.37: 2Ọb 4.42-44. Ṣùgbọ́n Jesu sọ fún àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ , "fún wọn oúnjẹ."

Àwọn ọmọ-ẹ̀yìn fún , "Èyí yóò wa owó iṣẹ́ ̀oṣù mẹ́jọ, ṣe a lọ fi èyí ra àkàrà fún àwọn ̀pọ̀ ènìyàn yìí láti jẹ."

38 Jesu tún béèrè , "Ìṣù àkàrà mélòó ni ̀yin ni lọ́wọ́? lọ ó."

Wọ́n padà jíṣẹ́ , "Ìṣù àkàrà márùn-ún àti ẹja méjì."

39 Nígbà náà ni Jesu sọ fún ̀pọ̀ ènìyàn náà a wọn jókòó lẹ́gbẹ̀̀gbẹ́ lórí koríko. 40 Lẹ́sẹ̀kan náà, wọ́n bẹ̀rẹ̀ í jókòó, àádọ́ta tàbí ọgọọgọ́rùn-ún. 41 6.41: Mk 14.22; Lk 24.30-31.Nígbà ó ìṣù àkàrà márùn-ún àti ẹja méjì náà, ó gbé ojú rẹ̀ sókè ̀run. Ó dúpẹ́ fún oúnjẹ náà, ó wọ́n wẹ́wẹ́, ó fún àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ láti gbé e kalẹ̀ síwájú àwọn ènìyàn náà àti àwọn ẹja méjì náà ni ó pín fún gbogbo wọn. 42 Gbogbo wọn jẹ àjẹyó. 43 Àwọn ọmọ-ẹ̀yìn agbọ̀n méjìlá ó kún fún àjẹkù àkàrà àti ti ẹja pẹ̀. 44 Àwọn ó jẹ́ àkàrà náà ìwọ̀n ẹgbẹ̀rún márùn-ún (5,000) ọkùnrin.

Veja também