Pular para o conteúdo
Publicidade

Òwe 6

16 Àwọn ohun mẹ́Olúwa kórìíra,

ohun méje ó jẹ́ ìríra i,

17 Ojú ìgbéraga,

ahọ́n ń parọ́

ọwọ́ ń ta ̀jẹ̀ aláìṣẹ̀ sílẹ̀,

18 ọkàn ń pète ohun búburú,

ẹsẹ̀ ó yára láti sáré sínú ìwà ìkà,

19 ajẹ́rìí èké ń irọ́ jáde lẹ́nu

àti ènìyàn ń ìjà sílẹ̀ láàrín àwọn ọmọ ìyá kan.

Estes versículos te tocaram? Ore agora!

+581 estão orando agora.

Junte-se à corrente de oração.

Veja também