Pular para o conteúdo
Publicidade

Provérbios 2

Èrè ìwà rere ọgbọ́n ń

1 Ọmọ mi, ìwọ gba ̀rọ̀ mi,

ìwọ pa òfin mi mọ́ inú rẹ,

2 ìwọ dẹtí rẹ sílẹ̀ ọgbọ́n

ìwọ fi ọkàn rẹ òye,

3 àní, ìwọ tọ ìmọ̀ lẹ́yìn,

ìwọ gbé ohùn rẹ sókè fún òye

4 ìwọ ṣàfẹ́rẹ̀ i fàdákà

ìwọ wa kiri ìṣúra a fi pamọ́.

5 Nígbà náà ni ìwọ yóò bẹ̀Olúwa,

ìwọ yóò ìmọ̀ Ọlọ́run.

6 Nítorí Olúwa ni ó ń fún ni ọgbọ́n,

láti ẹnu rẹ̀ ni ìmọ̀ àti òye ti ń .

Veja também