Pular para o conteúdo
Publicidade

Provérbios 5

18 Jẹ́ orísun rẹ ó ìbùkún;

ìwọ ó máa yọ nínú aya ìgbà èwe rẹ.

19 Abo àgbọ̀nrín dára, ìgalà ó wu ni jọjọ,

jẹ́ ọmú rẹ̀ ó máa fi ayọ̀ fún nígbà gbogbo,

o máa yọ̀ nínú ìfẹ́ rẹ̀ nígbàkígbà.

Veja também