Publicidade

Provérbios 27

1 ṣe yangàn nítorí ̀la

nítorí o mọ ohun ọjọ́ kan le è wáyé.

2 Jẹ́ ẹlòmíràn yìn ́ dípò ẹnu ara rẹ,

àní àlejò, ó ṣe ètè ìwọ fúnra rẹ̀.

3 Òkúta wúwo, erùpẹ̀ wúwo

ṣùgbọ́n ìbínú aṣiwèrè wúwo ju méjèèjì lọ.

4 Ìbínú ni ìkà, ìrunú burú púpọ̀

ṣùgbọ́n ta ni ó le è dúró níwájú owú?

5 Ìbániwí gbangba sàn

ju ìfẹ́ ìkọ̀kọ̀ lọ.

6 Òtítọ́ ni ọgbẹ́ ̀rẹ́,

ṣùgbọ́n ìfẹnukonu ̀ni ̀tàn.

7 Kódà oyin dùn lẹ́nu ẹni ó ti

ṣùgbọ́n òróǹró gan an dùn lẹ́nu ẹni ebi ń pa.

8 ẹyẹ ó ṣáko lọ kúrò níbi ìtẹ́ rẹ̀

ni ènìyàn ó ṣáko lọ kúrò ilé rẹ̀.

9 Ìpara olóòórùn dídùn àti tùràrí ń ayọ̀ sínú ọkàn

bẹ́̀ ni inú dídùn láti ̀dọ̀ ̀rẹ́ ń láti inú ìmọ̀ràn ó ṣàkóso.

10 ṣe kọ ̀rẹ́ rẹ àti ̀rẹ́ baba rẹ sílẹ̀,

ṣe lọ sílé arákùnrin rẹ nígbà ìdààmú

ó sàn o jẹ́ aládùúgbò ó súnmọ́ ni ju arákùnrin ó jìnnà ni.

11 Gbọ́n, ọmọ mi, o ayọ̀ sínú ọkàn mi

nígbà náà ni mo le gbogbo ẹni ó kẹ́gàn mi.

12 Ọlọ́gbọ́n ewu, ó fi ara pamọ́

ṣùgbọ́n aláìgbọ́n , kàkà ó dúró ó tẹ̀síwájú, ó jìyà rẹ̀.

13 Gba aṣọ ẹni ó ṣe onídùúró fún àjèjì

fi ṣe ̀ìdúró o ṣe onídùúró fún obìnrin oníṣekúṣe.

14 ènìyàn kan ń kígbe súre fún aládùúgbò rẹ òwúrọ̀

a ó á èpè.

15 Àyà ó máa ń dàbí

̀wààrà òjò ọjọ́ òjò ń rọ̀;

16 dídá a lẹ́kun dàbí ìgbà ènìyàn ń afẹ́fẹ́ lẹ́kun

tàbí ẹni ó gbá òróró.

17 irin ń pọ́n irin

bẹ́̀ ni ènìyàn kan ń pọ́n ẹlòmíràn .

18 Ẹni ó tọ́igi ̀pọ̀tọ́ yóò jẹ èso rẹ̀

ẹni ó fojú ̀rẹ̀ yóò gba ọlá.

19 omi ń ṣe àfihàn ojú, nígbà a ó

bẹ́̀ ni ọkàn ènìyàn ń ṣe àfihàn ènìyàn.

20 tẹ́ ikú àti ìparun lọ́rùn

bẹ́̀ pẹ̀ni ojú ènìyàn ìtẹ́lọ́rùn .

21 Iná fún fàdákà iná ìléru fún wúrà,

ṣùgbọ́n a ń dán ènìyàn nípa ìyìn ó ń gbà.

22 a tilẹ̀ gún aláìgbọ́n nínú odó,

fi ọmọ odó gún un èlùbọ́

ìwọ yóò le è yọ ìwà òmùgọ̀ rẹ̀ kúrò inú rẹ̀.

23 i dájú o mọ ipò àwọn agbo àgùntàn rẹ

bojútó àwọn agbo màlúù rẹ dáradára;

24 nítorí ọrọ̀ í pẹ́ lọ títí

adé í í lórí títí láéláé.

25 Nígbà a koríko, ewéko tuntun yóò jáde, a ó koríko àwọn orí òkè wọlé

26 àwọn àgùntàn yóò pèsè aṣọ fún ,

àti ewúrẹ́ yóò pèsè owó oko.

27 Ìwọ yóò ̀pọ̀lọpọ̀ wàrà ewúrẹ́

láti bọ́ àti ìdílé rẹ

àti láti tọ́àwọn ìránṣẹ́bìnrin rẹ.

Veja também

Publicidade
Bíblia Online Bíblia Online

Bíblia Online • Versão: 2026-06-28_14-13-17-