Publicidade

Provérbios 4

Ọgbọ́n ni o ga jùlọ

1 Tẹ́, ̀yin ọmọ mi, ̀kọ́ baba; fetísílẹ̀ o òye i.

2 Mo fún ̀kọ́ ó kooro,

nítorí náà, ṣe kọ ̀kọ́ mi sílẹ̀.

3 Nígbà mo jẹ́ ̀dọ́mọkùnrin ilé baba à ,

mo jẹ́ èwe, mo jẹ́ ̀kan ṣoṣo lọ́wọ́ ìyá mi.

4 Ó kọ́ mi ó ,

"Jẹ́ àyà rẹ ó gba ̀rọ̀ mi dúró,

pa òfin mi mọ́, ìwọ ó .

5 Gba ọgbọ́n, gba òye,

ṣe gbàgbé ̀rọ̀ mi tàbí o yẹsẹ̀ kúrò nínú rẹ̀.

6 ṣe kọ ọgbọ́n sílẹ̀, yóò dáàbò ́,

fẹ́ràn rẹ̀, yóò bojútó .

7 Ọgbọ́n ni ó ga ; nítorí náà gba ọgbọ́n.

ó tilẹ̀ gbogbo ohun o , gba òye.

8 Gbé e ga, yóò gbé ga

dìrọ̀ mọ́ ọn, yóò bu iyì fún .

9 Yóò fi òdòdó ̀ṣọ́ ẹwà orí rẹ

yóò fi adé ẹlẹ́fún ."

10 Tẹ́, ọmọ mi, gba ohun mo sọ,

ọjọ́ ayé è rẹ yóò gùn.

11 Mo tọ́ ṣọ́̀ti ọgbọ́n

mo lọ ̀ti tààrà.

12 Nígbà o rìn, ìgbésẹ̀ rẹ ìdíwọ́

nígbà o sáré, ìwọ yóò kọsẹ̀.

13 Di ̀kọ́ , ṣe jẹ́ ó lọ;

tọ́u rẹ̀ dáradára nítorí òun ni ìyè rẹ.

14 ṣe gbé ẹsẹ̀ rẹ ojú ọnà àwọn ènìyàn búburú

tàbí o rìn ̀àwọn ẹni ibi.

15 Yẹra fún un, ṣe rìn níbẹ̀;

yàgò fún un o ̀tìrẹ lọ.

16 Nítorí wọn le sùn àyàfi wọ́n ṣe ibi,

wọn tòògbé àyàfi wọ́n gbé ẹlòmíràn ṣubú.

17 Wọ́n ń jẹ oúnjẹ ìwà búburú

wọ́n ń mu wáìnì ìwà ìkà.

18 Ipa ̀olódodo dàbí àṣẹ̀ṣẹ̀yọ oòrùn

ń tànmọ́lẹ̀ i títí ọjọ́ fi kanrí

19 ṣùgbọ́n ̀ènìyàn búburú dàbí òkùnkùn biribiri;

wọn mọ ohun ó ń wọn kọsẹ̀.

20 Ọmọ mi, tẹ́ohun mo sọ;

fetísílẹ̀ dáradára ̀rọ̀ mi.

21 ṣe jẹ́ wọ́n mọ́ lójú

pa wọ́n mọ́ sínú ọkàn rẹ,

22 nítorí ìyè ni wọ́n jẹ́ fún gbogbo ẹni ó wọn

àti ìlera fún gbogbo ara ènìyàn.

23 Ju gbogbo nǹkan tókù lọ, pa ọkàn rẹ mọ́,

nítorí òun ni orísun ìyè.

24 àrékérekè kúrò ẹnu rẹ;

jẹ́ ̀rọ̀ ìsọkúsọ jìnnà réré ẹnu rẹ.

25 Jẹ́ ojú rẹ máa wo iwájú,

jẹ́ ìwo ojú rẹ máa wo ̀kánkán iwájú rẹ á.

26 4.26: (Gk): Hb 12.13. Kíyèsi ìrìn ẹsẹ̀ rẹ

rìn àwọn ̀ó dára nìkan.

27 ṣe sọ́tùn ún tàbí sósì;

pa ẹsẹ̀ rẹ mọ́ kúrò nínú ibi.

Veja também

Bíblia Online Bíblia Online

Bíblia Online • Versão: 2026-07-05_12-11-46-