Pular para o conteúdo
Publicidade

1 Samuẹli 4:11,17,22

11 Wọ́n gba àpótí ẹ̀rí Olúwa, àwọn ọmọkùnrin Eli méjèèjì sì kú, Hofini àti Finehasi.

17 Ọkùnrin tí ó mú ìròyìn náà wá dáhùn pé, "Israẹli sá níwájú àwọn Filistini, ìṣubú àwọn ọmọ-ogun náà sì pọ̀ lọ́pọ̀lọ́pọ̀ pẹ̀lú àwọn ọmọ rẹ méjèèjì, Hofini àti Finehasi, wọ́n kú, wọ́n sì ti gba àpótí ẹ̀rí Olúwa lọ."

22 Ó si wí pé, "Ògo kò sí fún Israẹli mọ́, nítorí ti a ti gbá àpótí Ọlọ́run."

Estes versículos te tocaram? Ore agora!

+581 estão orando agora.

Junte-se à corrente de oração.