Pular para o conteúdo
Publicidade

Eksodu 10

Ìyọnu Eṣú

1 Nígbà náà ni Olúwa sọ fún Mose , "Lọ ̀dọ̀ Farao, mo ti ṣé àyà Farao le àti àyà àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀, èmi o ba le ṣe àwọn iṣẹ́ ìyanu mi láàrín wọn. 2 ̀yin ki ó le sọ fún àwọn ọmọ yín àti àwọn ọmọ ọmọ yín; mo ti jẹ àwọn ará Ejibiti àti mo ti ṣe àwọn iṣẹ́ ìyanu láàrín wọn. ìwọ ba á le mọ̀ Èmi ni Olúwa."

Estes versículos te tocaram? Ore agora!

+581 estão orando agora.

Junte-se à corrente de oração.

Veja também