Pular para o conteúdo
Publicidade

Êxodo 20

3 20.3: Ek 20.23; De 5.7. "Ìwọ gbọdọ̀ ọlọ́run mìíràn pẹ̀mi.

4 20.4: Ek 20.23; 34.17; Le 19.4; 26.1; De 4.15-19; 5.8; 27.15. Ìwọ gbọdọ̀ ṣe ère fún ara yín, tàbí àwòrán ohun kan ń bẹ òkè ̀run, tàbí ti ohun kan ń bẹ ìsàlẹ̀ ilẹ̀, tàbí ti ohun kan ń bẹ nínú omi ìsàlẹ̀ ilẹ̀. 5 20.5,6: Ek 23.24; 34.6,7,14; De 4.24; 5.9,10; 7.9.Ìwọ gbọdọ̀ tẹ orí ara rẹ ba fún wọn, bẹ́̀ ni ìwọ gbọdọ̀ sìn wọ́n; nítorí Èmi Olúwa Ọlọ́run rẹ, Ọlọ́run owú ni , ń bẹ ̀ṣẹ̀ àwọn baba lára àwọn ọmọ, láti ìran kẹta títí ̀kẹrin nínú àwọn ó kórìíra mi. 6 Èmi a máa fi àánú hàn ẹgbẹẹgbẹ̀rún àwọn ó fẹ́ mi, wọ́n ń pa òfin mi mọ́.

7 20.7: Le 19.12; De 5.11. ṣe ṣi orúkọ Olúwa Ọlọ́run yín , torí ẹnikẹ́ni o ṣi orúkọ rẹ̀ yóò lọ láìjẹ̀bi.

8 20.8: Ek 23.12; 31.12-17; 34.21; 35.2,3; Le 19.3; De 5.12-15. Rántí ọjọ́ ìsinmi láti á mímọ́. 9 Ọjọ́ mẹ́ni ìwọ yóò fi ṣiṣẹ́, ìwọ ó ṣe gbogbo iṣẹ́ rẹ, 10 ṣùgbọ́n ọjọ́ keje ni ọjọ́ ìsinmi Olúwa Ọlọ́run rẹ: nínú rẹ̀ ìwọ gbọdọ̀ ṣe iṣẹ́kíṣẹ́ kan: ìwọ, àti ọmọ rẹ ọkùnrin àti ọmọ rẹ obìnrin, ọmọ ̀dọ̀ rẹ ọkùnrin àti ọmọ ̀dọ̀ rẹ obìnrin, àti ẹran ̀sìn rẹ, àti àlejò rẹ, ń bẹ nínú ibodè rẹ. 11 Nítorí ọjọ́ mẹ́ni Olúwa ̀run àti ayé, òkun àti ohun gbogbo ń bẹ nínú wọn, ó sinmi ọjọ́ keje: nítorí náà ni Olúwa ṣe bùkún ọjọ́ ìsinmi ó á mímọ́.

12 20.12-16: Mt 19.18,19; Mk 10.19; Lk 18.20. 20.12: Le 19.3; De 5.16; Mt 15.4; Mk 7.10; Ef 6.2. Bọ̀wọ̀ fún baba òun ìyá rẹ, ọjọ́ rẹ ó pẹ́ orí ilẹ̀ Olúwa Ọlọ́run rẹ fi fún .

13 20.13: Gẹ 9.6; Ek 21.12; Le 24.17; De 5.17; Mt 5.21; Jk 2.11. 20.13-17: Ro 13.9. Ìwọ gbọdọ̀ pànìyàn.

14 20.14: Le 20.10; De 5.18; Mt 5.27; Ro 7.7. Ìwọ gbọdọ̀ ṣe panṣágà.

15 20.15: Le 19.11; De 5.19. Ìwọ gbọdọ̀ jalè.

16 20.16: Ek 23.1; De 5.20. Ìwọ gbọdọ̀ jẹ́rìí èké ẹnìkejì rẹ.

17 20.17: De 5.21; Ro 7.7. Ìwọ gbọdọ̀ ṣe ojúkòkòrò ilé ẹnìkéjì rẹ. Ìwọ gbọdọ̀ ṣe ojúkòkòrò aya ẹnìkéjì rẹ, ọmọ ̀dọ̀ rẹ̀ ọkùnrin àti ọmọ ̀dọ̀ rẹ̀ obìnrin, akọ màlúù rẹ̀ àti kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ rẹ̀ àti ohun gbogbo í ṣe ti ẹnìkéjì rẹ."

Veja também