Pular para o conteúdo
Publicidade

1 Samuẹli 2

Àdúrà Hana

1 Hana gbàdúrà ,

"Ọkàn mi yọ̀ Olúwa;

ìwo agbára mi ni a gbé sókè Olúwa.

Ẹnu mi gbòòrò lórí àwọn ̀mi,

nítorí ti èmi yọ̀ ni ìgbàlà rẹ̀.

2 "ẹni ó mọ́ bi Olúwa;

ẹlòmíràn ṣe ìwọ;

àpáta bi Ọlọ́run wa.

3 "ṣe halẹ̀;

ṣe jẹ́ ìgbéraga ti ẹnu yín jáde

nítorí Ọlọ́run olùmọ̀ ni Olúwa,

láti ̀dọ̀ rẹ̀ ni a ti ń wọn ìwà.

4 "̀run àwọn alágbára ti ṣẹ́,

àwọn ó ṣe aláìlera ni a fi agbára àmùrè.

5 Àwọn ó yọ̀ fún oúnjẹ ti fi ara wọn ṣe alágbàṣe,

àwọn ebi ń pa ṣe aláìní.

bẹ́̀ àgàn fi méje.

Ẹni ó bímọ púpọ̀ di aláìlágbára.

6 "Olúwa pa ó sọ di ààyè;

ó sọ̀kalẹ̀ lọ isà òkú, ó gbé dìde.

7 Olúwa sọ di tálákà; ó sọ di ọlọ́rọ̀;

ó rẹ̀ sílẹ̀, ó gbé sókè.

8 Ó gbé tálákà sókè láti inú erùpẹ̀ ,

ó gbé alágbe sókè láti orí òkìtì eérú ,

láti wọn jókòó pẹ̀àwọn ọmọ-aládé,

láti mu wọn jogún ìtẹ́ ògo,

"Nítorí ̀wọ́n ayé ti Olúwa ni,

ó ti gbé ayé ka orí wọn.

9 Yóò pa ẹsẹ̀ àwọn ènìyàn mímọ́ rẹ̀ mọ́,

àwọn ènìyàn búburú ni yóò dákẹ́ òkùnkùn.

"Nípa agbára ọkùnrin yóò borí.

10 A ó fọ́ àwọn ̀Olúwa túútúú;

láti ̀run ni yóò sán àrá wọn;

Olúwa yóò ṣe ìdájọ́ òpin ayé.

"Yóò fi agbára fún ọba rẹ̀,

yóò si gbé ìwo ẹni àmì òróró rẹ̀ sókè."

Veja também