Pular para o conteúdo
Publicidade

Êxodo 18

17 Àna Mose a lóhùn , "Ohun o ń ṣe yìí dára. 18 Ìwọ àti àwọn ènìyàn ti ń tọ̀ ́ yìí yóò ara yín agara; iṣẹ́ yìí pọ̀fún , ìwọ nìkan a ṣe. 19 Nísinsin yìí, fetísílẹ̀ mi, èmi yóò gbà ́ ni ìmọ̀ràn, Ọlọ́run yóò pẹ̀rẹ. Ìwọ gbọdọ̀ jẹ́ aṣojú àwọn ènìyàn wọ̀nyí níwájú Ọlọ́run, ìwọ yóò èdè-àìyedè iwájú rẹ̀. 20 Kọ́ wọn òfin àti ìlànà Ọlọ́run, fi ̀igbe ayé ìwà-bí-Ọlọ́run hàn wọ́n àti iṣẹ́ wọn yóò máa ṣe. 21 Ṣa àwọn ó kún ojú òsùwọ̀n nínú gbogbo àwọn ènìyàn, àwọn bẹ̀Ọlọ́run, ti wọ́n jẹ́ olóòtítọ́, wọ́n kórìíra ìrẹ́jẹ; yàn wọ́n ṣe olórí, lórí ẹgbẹ̀rún ẹgbẹ̀rún, ọgọ́rùn-ún ọgọ́rùn-ún, àádọ́ta-dọ́ta àti mẹ́wàá mẹ́wàá. 22 Jẹ́ wọn ó máa ṣe ìdájọ́ àwọn ènìyàn ni gbogbo ìgbà, ṣùgbọ́n jẹ́ wọn ẹjọ́ ó nira fún wọn láti tọ̀ ́ ; wọn ó máa ẹjọ́ kéékèèké. Èyí ni yóò iṣẹ́ rẹ rọrùn, wọn yóò máa ràn ́ lọ́wọ́ lórí ìdájọ́ ṣíṣe. 23 ìwọ ṣe èyí, Ọlọ́run fi àṣẹ i fún bẹ́̀, àárẹ̀ tètè mu , àwọn ènìyàn wọ̀nyí yóò padà lọ ilé wọn ni àlàáfíà."

Veja também