Pular para o conteúdo
Publicidade

Eksodu 2

Ìbí Mose

1 Ó ṣe, ọkùnrin ará ilé Lefi kan fẹ́ ọmọbìnrin ará Lefi kan ni ìyàwó. 2 2.2: Ap 7.20; Hb 11.23.Obìnrin náà lóyún, ó ọmọkùnrin kan. Nígbà ó í ọmọ náà rẹwà, ó gbé ọmọ náà pamọ́ fún oṣù mẹ́ta. 3 Ṣùgbọ́n nígbà le è gbé e pamọ́ mọ́, ó fi ewé papirusi hun apẹ̀rẹ̀, ó fi ̀àti òjé igi sán apẹ̀rẹ̀ náà. Ó tẹ́ ọmọ náà sínú rẹ̀, ó gbe é inú eèsún ni etí odò Naili. 4 Arábìnrin rẹ̀ dúró ni òkèèrè láti wo ohun yóò ṣẹlẹ̀ ọmọ náà.

5 2.5,10: Ap 7.21. Nígbà náà ni ọmọbìnrin Farao sọ̀kalẹ̀ etí odò Naili láti wẹ̀, àwọn ọmọ ̀dọ̀ rẹ̀ ń rìn ni etí bèbè odò. Ó ri apẹ̀rẹ̀ náà ni àárín eèsún, ó rán ọmọ ̀dọ̀ rẹ̀ obìnrin kan láti lọ gbé e , 6 ó ṣí i, ó ọmọ náà. Ọmọ náà ń sọkún, àánú ọmọ náà ṣe é. Ó , "̀kan nínú àwọn ọmọ Heberu ni èyí."

7 Nígbà náà ni arábìnrin rẹ̀ béèrè lọ́wọ́ ọmọbìnrin Farao , "Ṣé èmi lọ ̀kan lára àwọn obìnrin Heberu fún láti tọ́ọmọ náà?"

8 Ó dáhùn , "Bẹ́̀ ni; lọ." Arábìnrin náà lọ, ó pe ìyá ọmọ náà . 9 Ọmọbìnrin Farao fún un , "Gba ọmọ yìí o tọ́rẹ̀ fún mi, èmi yóò san owó iṣẹ́ ̀ rẹ fún ." Ọmọbìnrin náà gbé ọmọ náà lọ, ó tọ́rẹ̀. 10 Nígbà ọmọ náà dàgbà, ó un tọ ọmọbìnrin Farao , ó di ọmọ rẹ̀. Ó pe orúkọ rẹ̀ Mose, ó , "Nítorí mo á jáde nínú omi."

Veja também