Pular para o conteúdo
Publicidade

Gẹnẹsisi 45:1,4,5,15

Josẹfu fi ara rẹ̀ hàn fún àwọn arákùnrin rẹ̀

1 45.1: Ap 7.13. Josẹfu kò sì le è pa á mọ́ra mọ́ níwájú gbogbo àwọn tí ó dúró tì í. Ó sì sọkún sókè tó bẹ́ẹ̀ tí àwọn tí ó wà ní àyíká gbọ́ ohun ẹkún rẹ̀. "Jẹ́ kí gbogbo ènìyàn kúrò ní ọ̀dọ̀ mi." Kò sì sí ẹnikẹ́ni lọ́dọ̀ rẹ̀ nígbà tí ó fi ara rẹ̀ hàn fún àwọn arákùnrin rẹ̀.

4 Nígbà náà ni Josẹfu wí fún àwọn arákùnrin rẹ̀ pé, "Ẹ súnmọ́ ọ̀dọ̀ mi." Nígbà tí wọ́n sì ti ṣe bẹ́ẹ̀, ó wí pé, "Èmi ni Josẹfu arákùnrin yín tí ẹ tà sí ilẹ̀ Ejibiti! 5 Ṣùgbọ́n báyìí, ẹ má ṣe banújẹ́, ẹ má sì ṣe bínú sí ara yín ní títà tí ẹ tà mí sí ìhín, nítorí, ọ̀nà àti gba ẹ̀mí yín là ni Ọlọ́run ṣe rán mi sí ìhín ṣáájú yín.

15 Ó sì tún fẹnu ko gbogbo àwọn arákùnrin rẹ̀ lẹ́nu, ó sì sọkún sí wọn lára. Lẹ́yìn èyí, Josẹfu àti àwọn arákùnrin rẹ̀ sọ̀rọ̀ pọ̀.

Estes versículos te tocaram? Ore agora!

+581 estão orando agora.

Junte-se à corrente de oração.