Pular para o conteúdo
Publicidade

Gẹnẹsisi 47

7 Nígbà náà ni Josẹfu Jakọbu baba rẹ̀ wọlé iwájú Farao. Lẹ́yìn ìgbà Jakọbu súre fún Farao tán. 8 Farao béèrè lọ́wọ́ Jakọbu , "Ọmọ ọdún mélòó ni ́?"

9 Jakọbu Farao lóhùn, "Ọdún ìrìnàjò ayé mi jẹ́ àádóje, ọjọ́ mi pọ̀, ó kún fún wàhálà, síbẹ̀ ì ì ti àwọn baba mi." 10 Nígbà náà ni Jakọbu tún súre fún Farao, ó jáde lọ kúrò níwájú rẹ̀.

11 Josẹfu fi baba rẹ̀ àti àwọn arákùnrin rẹ̀ ilẹ̀ Ejibiti, ó fún wọn ohun ìní ibi ó dára ilẹ̀ náà, agbègbè Ramesesi Farao ti pàṣẹ. 12 Josẹfu pèsè oúnjẹ fún baba rẹ̀ àti àwọn arákùnrin rẹ̀ àti gbogbo ìdílé baba rẹ̀ gẹ́gẹ́ bi iye àwọn ọmọ wọn.

Estes versículos te tocaram? Ore agora!

+581 estão orando agora.

Junte-se à corrente de oração.

Veja também