Publicidade

Josué 3

14 Nígbà àwọn ènìyàn gbéra láti ibùdó láti kọjá nínú odò Jordani, àwọn àlùfáà ó ru àpótí ̀náà ń lọ níwájú wọn. 15 Odò Jordani máa ń kíkún gbogbo ìgbà ìkórè. Ṣùgbọ́n àwọn àlùfáà ó ru àpótí ̀ti odò Jordani ẹsẹ̀ wọn kan etí omi, 16 omi ń ti òkè sàn dúró. Ó gbá jọ òkìtì òkèèrè, ìlú a ń Adamu, ó tòsí Saretani; nígbà omi ń sàn lọ sínú Òkun aginjù (ti o túmọ̀ Òkun Iyọ̀) kúrò pátápátá. Bẹ́̀ ni àwọn ènìyàn kọjá òdìkejì ìdojúkọ Jeriko. 17 Àwọn àlùfáà ó ru àpótí ̀Olúwa dúró ṣinṣin lórí ilẹ̀ gbígbẹ àárín Jordani, nígbà gbogbo àwọn ọmọ Israẹli ń kọjá títí gbogbo orílẹ̀-èdè náà fi rékọjá nínú odò Jordani lórí ilẹ̀ gbígbẹ.

Veja também

Bíblia Online Bíblia Online

Bíblia Online • Versão: 2026-07-05_12-11-46-