Pular para o conteúdo
Publicidade

Neemias 13

12 Gbogbo Juda ìdámẹ́wàá ọkà, wáìnì tuntun àti òróró sínú yàrá ìkó nǹkan pamọ́ . 13 Mo fi àlùfáà Ṣelemiah, Sadoku akọ̀àti ọmọ Lefi kan orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Pedaiah ṣe alákòóso àwọn yàrá ìkó nǹkan pamọ́ . Mo yan Hanani ọmọ Sakkuri, ọmọ Mattaniah olùrànlọ́wọ́ wọn. Àwọn ènìyàn wọ̀nyí ni a àwọn ṣé e gbẹ́kẹ̀. Àwọn ni a yàn láti máa pín ohun èlò fún àwọn arákùnrin wọn.

14 Rántí ì mi fún èyí, Ọlọ́run mi, o ṣe gbàgbé ohun mo fi òtítọ́ ṣe fún ilé Ọlọ́run mi yìí àti fún iṣẹ́ rẹ̀ gbogbo.

Veja também