Pular para o conteúdo
Publicidade

1 Samuel 20

41 ọmọdékùnrin náà ti lọ tán, Dafidi dìde láti ibi ìhà gúúsù òkúta náà, ó wólẹ̀, ó tẹríba ìdojúbolẹ̀ lẹ́̀mẹ́ta fún Jonatani, wọ́n fi ẹnu ko ara wọn lẹ́nu, wọ́n jùmọ̀ sọkún, èkínní pẹ̀èkejì rẹ̀, ṣùgbọ́n Dafidi sọkún púpọ̀ .

42 Jonatani fún Dafidi , "Máa lọ àlàáfíà, o ti jẹ́ àwa méjèèjì jùmọ̀ búra ni orúkọ Olúwa , Ki Olúwa ó láàrín èmi àti ìwọ, láàrín irú-ọmọ mi àti láàrín irú-ọmọ rẹ̀ láéláé.’ " Òun dìde, ó lọ kúrò: Jonatani lọ ìlú.

Veja também