Pular para o conteúdo
Publicidade

Gênesis 6

Ìkún omi

1 6.1-4: Jb 1.6; 2.1. Nígbà ènìyàn bẹ̀rẹ̀ pọ̀ si orí ilẹ̀, wọ́n àwọn ọmọbìnrin. 2 Àwọn ọmọ Ọlọ́run i àwọn ọmọbìnrin ènìyàn lẹ́, wọ́n fẹ́ èyíkéyìí ó wọ́n ṣe aya. 3 Nígbà náà ni Olúwa , "Èémí ìyè mo sínú ènìyàn máa gbé inú ènìyàn títí láé, nítorí ẹran-ara à ni òun, ọgọ́ọdún ni ọjọ́ rẹ̀ yóò jẹ́."

4 6.4: Nu 13.33. Àwọn òmíràn láyé ọjọ́ wọ̀n-ọn-nì, àti lẹ́yìn ìgbà náà; nígbà àwọn ọmọ Ọlọ́run lọ àwọn ọmọbìnrin ènìyàn lòpọ̀ wọ́n bímọ fún wọn. Àwọn náà ni ó di akọni àti olókìkí ìgbà náà.

5 Olúwa ìwà búburú ènìyàn ti ń gbilẹ̀ si, àti gbogbo èrò inú rẹ̀ kìkì ibi ni, ìgbà gbogbo. 6 Inú Olúwa bàjẹ́ gidigidi nítorí ó ènìyàn ayé, ọkàn rẹ̀ gbọgbẹ́. 7 Nítorí náà, Olúwa , "Èmi yóò pa ènìyàn mo ti run kúrò lórí ilẹ̀, ènìyàn àti ẹranko, àti ohun ń rákò, àti ẹyẹ ojú ̀run, nítorí inú mi bàjẹ́ mo ti wọn." 8 Ṣùgbọ́n, Noa ojúrere Olúwa.

Noa àti ìkún omi

9 6.9: 2Pt 2.5. Wọ̀nyí ni ìtàn Noa.

Noa nìkan ni ó jẹ́ olóòótọ́ ènìyàn àti ẹni ó ìgbà ayé rẹ̀, ó fi òtítọ́ Ọlọ́run rìn.

Veja também