Pular para o conteúdo
Publicidade

1 Ọba 2

Dafidi pàṣẹ fún Solomoni

1 Nígbà ọjọ́ ikú Dafidi súnmọ́ etílé, ó pàṣẹ fún Solomoni ọmọ rẹ̀.

2 Ó , "Èmi ti fẹ́ lọ ̀gbogbo ayé, nítorí náà jẹ́ alágbára o fi ara rẹ hàn ọkùnrin, 3 o wòye ohun Olúwa Ọlọ́run rẹ béèrè, rìn ̀rẹ̀, o pa àṣẹ àti òfin rẹ̀ mọ́, àti ìdájọ́ rẹ, àti ̀rẹ̀ gẹ́gẹ́ a ti kọ ́ nínú ìwé òfin Mose, nítorí ìwọ ó le è máa ṣe rere ohun gbogbo ìwọ ṣe, àti ibikíbi ìwọ lọ, 4 Olúwa ó pa ìlérí rẹ̀ ó sọ nípa tèmi mọ́ , àwọn ọmọ rẹ kíyèsi ̀wọn, wọ́n fi gbogbo àyà wọn àti ọkàn wọn rìn níwájú mi òtítọ́, o yóò kùnà láti ọkùnrin kan lórí ìtẹ́ Israẹli.

Veja também