Pular para o conteúdo
Publicidade

Gênesis 12

2 12.2: Gẹ 15.5; 17.4,5; 18.18; 22.17; 28.14; 32.12; 35.11; 46.3. "Èmi yóò sọ ́ di orílẹ̀-èdè ńlá,

èmi yóò bùkún fún ;

èmi yóò sọ orúkọ rẹ di ńlá,

ìbùkún ni ìwọ yóò jásí.

3 12.3: Gẹ 18.18; 22.17,18; 26.4; 28.14; Ga 3.8. Èmi yóò bùkún fún àwọn ó súre fún ,

ẹni ó fi ́ ni Èmi yóò fi ;

nínú rẹ ni a ó bùkún

gbogbo ìdílé ayé."

Veja também