Pular para o conteúdo
Publicidade

Gẹnẹsisi 49

3 "Reubeni, ìwọ ni àkọ́mi,

agbára mi, ìpilẹ̀ṣẹ̀ ipá mi,

títayọ ọlá àti títayọ agbára.

4 Ẹni ríru omi Òkun, ìwọ yóò tayọ mọ́,

nítorí ìwọ gun ibùsùn baba rẹ,

lórí àkéte mi, ìwọ á jẹ́

(ìwọ ̀kan nínú àwọn aya baba rẹ lòpọ̀).

Veja também