Pular para o conteúdo
Publicidade

Jó 42

10 Olúwa ìgbèkùn Jobu padà, nígbà ó gbàdúrà fún àwọn ̀rẹ́ rẹ̀; Olúwa bùsi ohun gbogbo ti Jobu ìṣẹ́po méjì ohun ó tẹ́lẹ̀ . 11 Nígbà náà gbogbo àwọn arákùnrin rẹ̀, àti gbogbo àwọn arábìnrin rẹ̀, àti gbogbo àwọn ó ti ṣe ojúlùmọ̀ rẹ̀ ; wọ́n a jẹun nínú ilé rẹ̀. Wọ́n ṣe ìdárò rẹ̀, wọ́n ṣìpẹ̀ fún un nítorí ibi gbogbo Olúwa ti a. Olúkúlùkù ènìyàn pẹ̀fún un ẹyọ owó kọ̀̀kan àti olúkúlùkù ni òrùka wúrà etí kọ̀̀kan.

12 Bẹ́̀ ni Olúwa bùkún ìgbẹ̀yìn Jobu ju ìṣáájú rẹ̀ lọ; ẹgbàá méje (14,000) àgùntàn, ẹgbẹ̀rún mẹ́(6,000) ìbákasẹ, àti ẹgbẹ̀rún (1,000) àjàgà ̀màlúù, àti ẹgbẹ̀rún (1,000) abo kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́. 13 Ó ọmọkùnrin méje àti ọmọbìnrin mẹ́ta. 14 Ó sọ orúkọ àkọ́Jemima, àti orúkọ èkejì ni Kesia àti orúkọ ̀kẹta Kereni-Happuki. 15 Àti gbogbo ilẹ̀ náà, a obìnrin ó ẹwà ọmọ Jobu; baba wọ́n pínlẹ̀ fún wọn nínú àwọn arákùnrin wọn.

16 Lẹ́yìn èyí Jobu ayé ogóje ọdún, ó àwọn ọmọ rẹ̀ ọkùnrin àti ọmọ ọmọ rẹ̀ ọkùnrin, àní ìran mẹ́rin. 17 Bẹ́̀ ni Jobu , ó gbó, ó kún fún ọjọ́ púpọ̀.

Veja também