Pular para o conteúdo
Publicidade

Levítico 18

6 " Ẹnikẹ́ni nínú yín gbọdọ̀ súnmọ́ ìbátan rẹ̀ láti a lòpọ̀. Èmí ni Olúwa.

7 18.7: Le 20.11. " Ìwọ gbọdọ̀ tàbùkù baba rẹ nípa bíbá ìyá rẹ lòpọ̀, ìyá rẹ̀ ni, ìwọ gbọdọ̀ a lòpọ̀.

8 " Ìwọ gbọdọ̀ tàbùkù baba rẹ nípa bíbá ìyàwó baba rẹ lòpọ̀, nítorí ìhòhò baba rẹ ni.

9 18.9,11: Le 20.17; De 27.22. " Ìwọ gbọdọ̀ arábìnrin rẹ ó jẹ́ ọmọ ìyá rẹ lòpọ̀, yálà a i nílé yín tàbí lóde.

10 " Ìwọ gbọdọ̀ ọmọbìnrin, ọmọ rẹ ọkùnrin lòpọ̀ tàbí ọmọbìnrin ọmọ rẹ obìnrin lòpọ̀ nítorí ìhòhò wọn, ìhòhò ìwọ fúnra rẹ̀ ni.

11 " Ìwọ gbọdọ̀ ọmọbìnrin aya baba rẹ lòpọ̀; èyí a fún baba rẹ nítorí arábìnrin rẹ ni.

12 18.12: Le 20.19. " Ìwọ gbọdọ̀ arábìnrin baba rẹ lòpọ̀ nítorí ìbátan baba rẹ ni.

13 " Ìwọ gbọdọ̀ arábìnrin màmá rẹ lòpọ̀ nítorí ìbátan ìyá rẹ ni.

14 18.14: Le 20.20. " Ìwọ gbọdọ̀ tàbùkù arákùnrin baba rẹ nípa sísún mọ́ aya rẹ̀ láti a lòpọ̀ nítorí ìyàwó ̀gbọ́n baba rẹ ni.

15 18.15: Le 20.12. " Ìwọ gbọdọ̀ ọmọ àna obìnrin rẹ lòpọ̀ nítorí aya ọmọ rẹ ni. ṣe a lòpọ̀.

16 18.16: Le 20.21. " ṣe aya ̀gbọ́n rẹ ọkùnrin lòpọ̀ nítorí yóò tàbùkù ̀gbọ́n rẹ.

17 18.17: Le 20.14. " ṣe ìyá àti ọmọ rẹ obìnrin lòpọ̀, bẹ́̀ ni ìwọ gbọdọ̀ ọmọbìnrin ọmọkùnrin rẹ tàbí ọmọbìnrin ọmọbìnrin rẹ lòpọ̀ nítorí ìbátan rẹ tímọ́tímọ́ ni: nítorí àbùkù ni.

18 " ṣe fẹ́ àbúrò ìyàwó rẹ obìnrin aya gẹ́gẹ́ orogún tàbí a lòpọ̀, nígbà ìyàwó rẹ láààyè.

19 18.19: Le 15.24; 20.18. " ṣe súnmọ́ obìnrin láti a lòpọ̀ nígbà ó ń ṣe nǹkan oṣù, nítorí àkókò àìmọ́ ni.

20 " Ìwọ gbọdọ̀ aya aládùúgbò rẹ lòpọ̀, ìwọ ba à ba ara rẹ jẹ́ pẹ̀rẹ̀.

21 18.21: Le 20.2-5. " Ìwọ gbọdọ̀ fi èyíkéyìí nínú àwọn ọmọ rẹ ẹbọ lórí pẹpẹ òrìṣà Moleki, o tipa bẹ́̀ ba orúkọ Ọlọ́run rẹ jẹ́. Èmi ni Olúwa.

22 18.22: Le 20.13; De 23.18. " Ìwọ gbọdọ̀ ọkùnrin lòpọ̀ ìgbà ènìyàn ń obìnrin lòpọ̀: ìríra ni èyí jẹ́.

23 18.23: Ek 22.19; Le 20.15,16; De 27.21. " Ìwọ gbọdọ̀ ẹranko lòpọ̀ ìwọ ba à ba ara rẹ jẹ́. Obìnrin gbọdọ̀ jọ̀wọ́ ara rẹ̀ sílẹ̀ fún ẹranko láti a lòpọ̀, ohun lòdì ni.

Veja também