2 Gbogbo ọmọ Israẹli sì kùn sí Mose àti Aaroni, gbogbo ìjọ ènìyàn Israẹli sì wí fún wọn pé, "Àwa ìbá kúkú ti kú ní ilẹ̀ Ejibiti. Tàbí kí a kúkú kú sínú aginjù yìí. 4 Wọ́n sì sọ fún ara wọn pé, "Ẹ jẹ́ kí á yan olórí kí á sì padà sí Ejibiti."
Publicidade