Solomoni kọ́ ilé Olúwa
1 3.1-13: 1Ọb 6.1-28. Nígbà náà, Solomoni bẹ̀rẹ̀ sí ní kọ́ ilé Olúwa ní Jerusalẹmu lórí òkè Moria, níbi tí Olúwa ti farahan baba a rẹ̀ Dafidi. Ní orí ilẹ̀ ìpakà Arauna ará Jebusi, ibi tí Dafidi pèsè.

+581 estão orando agora.
Junte-se à corrente de oração.