Pular para o conteúdo
Publicidade

Isaiah 14:12-15

12 Báwo ni ìwọ ṣe ṣubú lulẹ̀ láti ọ̀run wá,

ìwọ ìràwọ̀ òwúrọ̀, ọmọ òwúrọ̀ náà!

A ti sọ ọ́ sílẹ̀ sínú ayé,

ìwọ tí o ti tẹ orí àwọn orílẹ̀-èdè ba rí!

13 Ìwọ sọ nínú ọkàn rẹ pé,

"Èmi yóò gòkè lọ sí ọ̀run;

èmi yóò gbé ìtẹ́ mi sókè

ga ju àwọn ìràwọ̀ Ọlọ́run,

Èmi yóò gúnwà ní orí òkè àpéjọ

ní ṣóńṣó orí òkè mímọ́.

14 Èmi yóò gòkè lọ rékọjá àwọn àwọsánmọ̀;

èmi yóò ṣe ara mi gẹ́gẹ́ bí Ọ̀gá-ògo."

15 Ṣùgbọ́n a ti rẹ̀ ọ́ sílẹ̀ wọ inú ibojì lọ

lọ sí ìsàlẹ̀ ọ̀gbun.

Estes versículos te tocaram? Ore agora!

+581 estão orando agora.

Junte-se à corrente de oração.