Pular para o conteúdo
Publicidade

Isaías 40

28 Ìwọ ì mọ̀?

Ìwọ ì gbọ́?

Olúwa òun ni Ọlọ́run ayérayé,

Ẹlẹ́dàá gbogbo ìpẹ̀kun ilẹ̀ ayé.

Agara yóò da bẹ́̀ ni ṣàárẹ̀,

àti òye rẹ̀ ni ẹnikẹ́ni le ṣe òdínwọ̀n rẹ̀.

29 Ó ń fi agbára fún àwọn aláàárẹ̀

ó fi kún agbára àwọn agara .

30 Àní, ó ń rẹ̀ wọ́n àwọn ̀dọ́, wọ́n ń rẹ̀wẹ̀,

àwọn ̀dọ́mọkùnrin ń kọsẹ̀ wọ́n ṣubú;

31 ṣùgbọ́n àwọn ó gbẹ́kẹ̀Olúwa

yóò sọ agbára wọn di ̀tun.

Wọn yóò fìyẹ́ lókè idì;

wọn yóò sáré àárẹ̀ wọn,

wọn yóò rìn òòyì kọ́ wọn.

Veja também