Pular para o conteúdo
Publicidade

Isaiah 57:15

15 57.15: Mt 5.3. Nítorí èyí ni ohun tí Ẹni gíga àti ọlọ́lá jùlọ wí

ẹni tí ó wà títí láé, tí orúkọ rẹ̀ jẹ́ mímọ́:

"Mo ń gbé ní ibi gíga àti ibi mímọ́,

ṣùgbọ́n pẹ̀lú ẹni n nì tí ó ní ìròbìnújẹ́ àti ẹ̀mí ìrẹ̀lẹ̀,

láti sọ ẹ̀mí onírẹ̀lẹ̀ náà jí

àti láti sọ ẹ̀mí oníròbìnújẹ́ n nì jí.

Estes versículos te tocaram? Ore agora!

+581 estão orando agora.

Junte-se à corrente de oração.