Pular para o conteúdo
Publicidade

Isaiah 6:3,5

3 6.3: If 4.8.Wọ́n sì ń kọ sí ara wọn wí pé,

"Mímọ́, mímọ́, mímọ́ ni Olúwa àwọn ọmọ-ogun

gbogbo ayé kún fún ògo rẹ̀."

5 Mo kígbe pé, "Ègbé ni fún mi! Mo ti gbé!" Nítorí mo jẹ́ ènìyàn aláìmọ́ ètè, mo sì ń gbé láàrín àwọn ènìyàn aláìmọ́ ètè, ojú mi sì ti rí ọba, Olúwa àwọn ọmọ-ogun jùlọ.

Estes versículos te tocaram? Ore agora!

+581 estão orando agora.

Junte-se à corrente de oração.