Pular para o conteúdo
Publicidade

Isaiah 60:1-3

Ògo Sioni

1 "Dìde, tànmọ́lẹ̀, nítorí ìmọ́lẹ̀ rẹ ti dé,

ògo Olúwa sì ràdàbò ọ́.

2 Kíyèsi i, òkùnkùn bo ilẹ̀ ayé

òkùnkùn biribiri sì wà lórí àwọn ènìyàn,

ṣùgbọ́n Olúwa ràn bò ọ́

ògo rẹ̀ sì farahàn lórí i rẹ.

3 Àwọn orílẹ̀-èdè yóò wá sí ìmọ́lẹ̀ rẹ,

àti àwọn ọba sí ìmọ́lẹ̀ òwúrọ̀ rẹ.

Estes versículos te tocaram? Ore agora!

+581 estão orando agora.

Junte-se à corrente de oração.