Publicidade

Isaías 40

29 Ó ń fi agbára fún àwọn aláàárẹ̀

ó fi kún agbára àwọn agara .

30 Àní, ó ń rẹ̀ wọ́n àwọn ̀dọ́, wọ́n ń rẹ̀wẹ̀,

àwọn ̀dọ́mọkùnrin ń kọsẹ̀ wọ́n ṣubú;

31 ṣùgbọ́n àwọn ó gbẹ́kẹ̀Olúwa

yóò sọ agbára wọn di ̀tun.

Wọn yóò fìyẹ́ lókè idì;

wọn yóò sáré àárẹ̀ wọn,

wọn yóò rìn òòyì kọ́ wọn.

Veja também

Bíblia Online Bíblia Online

Bíblia Online • Versão: 2026-07-05_19-25-13-