Pular para o conteúdo
Publicidade

Isaiah 61

2 láti kéde ọdún ojúrere Olúwa

àti ọjọ́ ̀san ti Ọlọ́run wa,

láti tu àwọn ń ṣọ̀fọ̀ nínú,

3 àti láti pèsè fún àwọn inú wọn bàjẹ́ Sioni

láti wọn ládé ẹwà dípò eérú,

òróró ayọ̀ dípò ̀fọ̀,

àti aṣọ ìyìn dípò ìpòrúru ọkàn.

A ó wọ́n igi óákù òdodo,

irúgbìn Olúwa

láti fi ọláńlá rẹ̀ hàn.

Veja também