Pular para o conteúdo
Publicidade

Isaiah 61

Ọdún ojúrere Olúwa

1 61.1-2: Mt 11.5; Lk 4.18-19; 7.22. ̀Olúwa Olódùmarè lára mi

nítorí Olúwa ti fi àmì òróró yàn

láti wàásù ìyìnrere fún àwọn tálákà.

Ó ti rán mi láti ṣe àwòtán oníròbìnújẹ́

láti kéde ìdásílẹ̀ fún àwọn ìgbèkùn

àti ìtúsílẹ̀ kúrò nínú òkùnkùn fún àwọn ẹlẹ́wọ̀n,

2 láti kéde ọdún ojúrere Olúwa

àti ọjọ́ ̀san ti Ọlọ́run wa,

láti tu àwọn ń ṣọ̀fọ̀ nínú,

3 àti láti pèsè fún àwọn inú wọn bàjẹ́ Sioni

láti wọn ládé ẹwà dípò eérú,

òróró ayọ̀ dípò ̀fọ̀,

àti aṣọ ìyìn dípò ìpòrúru ọkàn.

A ó wọ́n igi óákù òdodo,

irúgbìn Olúwa

láti fi ọláńlá rẹ̀ hàn.

Estes versículos te tocaram? Ore agora!

+581 estão orando agora.

Junte-se à corrente de oração.

Veja também