Pular para o conteúdo
Publicidade

Isaías 63

16 Ṣùgbọ́n ìwọ ni baba wa,

ó tilẹ̀ jẹ́ Abrahamu mọ̀

tàbí Israẹli mọ ẹni à á ṣe;

ìwọ, Olúwa ni Baba wa,

Olùràpadà wa láti ìgbà n ni orúkọ rẹ.

Veja também