Pular para o conteúdo
Publicidade

Saamu 103:15-18

15 Bí ó ṣe ti ènìyàn ni, ọjọ́ rẹ̀ dàbí koríko,

ó gbilẹ̀ bí ìtànná ewéko igbó,

16 afẹ́fẹ́ fẹ́ kọjá lọ lórí rẹ̀,

kò sì rántí ibùjókòó rẹ̀ mọ́.

17 103.17: Lk 1.50. Ṣùgbọ́n láti ayérayé ni ìfẹ́

Olúwa ti wà pẹ̀lú àwọn tí ó bẹ̀rù rẹ̀,

àti òdodo rẹ̀ wà láti ọmọdọ́mọ,

18 sí àwọn tí ó pa májẹ̀mú rẹ̀ mọ́

àti àwọn tí ó rántí òfin rẹ̀ láti ṣe wọ́n.

Estes versículos te tocaram? Ore agora!

+581 estão orando agora.

Junte-se à corrente de oração.