Pular para o conteúdo
Publicidade

Saamu 117

1 117.1: Ro 15.11. Ẹ yin Olúwa, gbogbo ẹ̀yin orílẹ̀-èdè;

ẹ pòkìkí rẹ̀, gbogbo ẹ̀yin ènìyàn.

2 Nítorí ìfẹ́ ńlá rẹ̀ tí ó ní sí wa,

àti òtítọ́ Olúwa dúró láéláé.

Ẹ yin Olúwa!

Estes versículos te tocaram? Ore agora!

+581 estão orando agora.

Junte-se à corrente de oração.