Pular para o conteúdo
Publicidade

Saamu 116

6 Olúwa pa àwọn ọlọ́kàn fífúyẹ́ mọ́

nígbà mo nínú àìní ńlá, ó gbà .

7 Padà, ìwọ ọkàn mi, ibi ìsinmi rẹ,

nítorí Olúwa ṣe dáradára .

8 Nítorí ìwọ, Olúwa, ti gba ọkàn mi

kúrò lọ́wọ́ ikú,

ojú mi kúrò lọ́wọ́ omijé,

àti ẹsẹ̀ mi kúrò lọ́wọ́ ìṣubú,

9 nítorí èmi yóò máa rìn níwájú Olúwa

ilẹ̀ alààyè.

Estes versículos te tocaram? Ore agora!

+581 estão orando agora.

Junte-se à corrente de oração.

Veja também