Pular para o conteúdo
Publicidade

Saamu 143

10 Kọ́ mi láti ṣe ìfẹ́ rẹ,

nítorí ìwọ ni Ọlọ́run mi

jẹ́ ̀rẹ dídára

darí mi ilẹ̀ ó tẹ́.

11 Nítorí orúkọ rẹ, Olúwa, sọ mi di ààyè;

nínú òdodo rẹ, ọkàn mi jáde nínú wàhálà.

Estes versículos te tocaram? Ore agora!

+581 estão orando agora.

Junte-se à corrente de oração.

Veja também