Pular para o conteúdo
Publicidade

Salmos 145

11 Wọn yóò sọ ògo ìjọba rẹ

wọn yóò sọ̀rọ̀ agbára rẹ,

12 gbogbo ènìyàn le mọ iṣẹ́ agbára rẹ̀

àti ọláńlá ìjọba rẹ ó lógo.

13 Ìjọba rẹ ìjọba ayérayé ni,

àti ìjọba rẹ gbogbo ìrandíran.

Veja também