Pular para o conteúdo
Publicidade

Saamu 37

39 Ìgbàlà àwọn onídùúró ṣinṣin láti ̀dọ̀ Olúwa;

òun ni ààbò wọn ìgbà ìpọ́njú

40 Olúwa yóò ràn wọ́n lọ́wọ́ yóò gbà wọ́n;

yóò gbà wọ́n lọ́wọ́ ènìyàn búburú, yóò gbà wọ́n ,

nítorí wọ́n gbẹ́kẹ̀e.

Estes versículos te tocaram? Ore agora!

+581 estão orando agora.

Junte-se à corrente de oração.

Veja também