Publicidade

Salmos 42

Fún adarí orin. Maskili ti àwọn ọmọ Kora.

1 àgbọ̀nrín ti ń hẹlẹ ipa odò omi,

bẹ́̀ ni ọkàn mi ń hẹlẹ Ọlọ́run.

2 Òùngbẹ Ọlọ́run ń gbẹ ọkàn mi, fún Ọlọ́run alààyè.

Nígbà wo ni èmi ó lọ Ọlọ́run?

3 Oúnjẹ mi ni omijé mi

̀sán àti òru,

nígbà àwọn ènìyàn ń fún mi gbogbo ọjọ́ ,

"Ọlọ́run rẹ ?"

4 Nígbà mo rántí nǹkan yìí,

èmi ọkàn mi jáde nínú mi:

èmi ti ̀pọ̀ ìjọ ènìyàn lọ,

èmi wọn lọ ilé Ọlọ́run

pẹ̀ohùn ayọ̀ àti ìyìn,

pẹ̀̀pọ̀ ènìyàn ń pa ọjọ́ mímọ́ mọ́.

5 Èéṣe o fi ń rẹ̀wẹ̀, ìwọ ọkàn mi?

Èéṣe ara rẹ fi lélẹ̀ nínú mi?

Ìwọ ṣe ìrètí ti Ọlọ́run,

nítorí èmi yóò à máa yìn ín,

Olùgbàlà mi àti Ọlọ́run mi.

6 Ọlọ́run mi, ọkàn mi ń rẹ̀wẹ̀nínú mi:

nítorí náà, èmi ó rántí rẹ

láti ilẹ̀ Jordani ,

láti Hermoni láti òkè Mibsari.

7 Ibú omi ń pe ibú omi

nípa híhó omi ṣíṣàn rẹ̀

gbogbo rírú omi àti bíbì omi rẹ̀

mọ́lẹ̀.

8 ̀sán Olúwa ran ìfẹ́ rẹ̀,

àti ni àṣálẹ́ ni orin rẹ̀ pẹ̀mi

àdúrà Ọlọ́run ayé mi.

9 Èmi fún Ọlọ́run àpáta mi,

"Èéṣe ìwọ fi gbàgbé mi?

Èéṣe èmi o fi máa rìn nínú ìbànújẹ́,

nítorí ìnilára ̀?"

10 ẹni idà egungun mi ni ̀gàn

àwọn ̀mi ń gàn ,

wọn ti ń béèrè gbogbo ọjọ́.

"Níbo ni Ọlọ́run rẹ ?"

11 Èéṣe ìwọ fi ń rẹ̀wẹ̀, ìwọ ọkàn mi?

Èéṣe ara rẹ fi lélẹ̀ nínú mi?

Fi ìrètí rẹ sínú Ọlọ́run,

nítorí èmi yóò máa yìn ín, Òun ni

Olùgbàlà mi àti Ọlọ́run mi.

Veja também

Bíblia Online Bíblia Online

Bíblia Online • Versão: 2026-07-05_12-11-46-