Pular para o conteúdo
Publicidade

Saamu 17

6 Èmi ́, Ọlọ́run, nítorí ìwọ yóò mi lóhùn

dẹ etí rẹ mi o gbọ́ àdúrà mi.

7 Fi ìṣeun ìyanu ìfẹ́ ńlá rẹ hàn

ìwọ ó fi ọwọ́ ̀tún rẹ gba àwọn ó gbẹ́kẹ̀

lọ́wọ́ àwọn ̀ó dìde wọn.

8 Pa mọ́ ẹyin ojú rẹ;

fi pamọ́ abẹ́ òjìji ìyẹ́ apá rẹ,

9 lọ́wọ́ àwọn ènìyàn búburú ń fóròó mi,

kúrò ọwọ́ àwọn ̀apani ó mi .

Estes versículos te tocaram? Ore agora!

+581 estão orando agora.

Junte-se à corrente de oração.

Veja também