Pular para o conteúdo
Publicidade

Salmos 32

1 32.1-2: Ro 4.7-8. Ìbùkún ni fún àwọn

a dárí ìrékọjá wọn ,

a bo ̀ṣẹ̀ wọn mọ́lẹ̀.

2 Ìbùkún ni fún ọkùnrin náà

ẹni Olúwa ka ̀ṣẹ̀ rẹ̀ i lọ́rùn

àti nínú ̀ẹni ̀tàn.

3 Nígbà mo dákẹ́,

egungun mi di gbígbó dànù

nípa ìkérora mi gbogbo ọjọ́.

4 Nítorí ni ̀sán àti òru

ọwọ́ rẹ̀ wúwo mi lára;

agbára mi gbẹ tán

gẹ́gẹ́ ooru ̀̀rùn. Sela.

5 Èmi jẹ́wọ́ ̀ṣẹ̀ mi

àti èmi fi àìṣòdodo mi pamọ́.

Èmi , "Èmi yóò jẹ́wọ́

̀ṣẹ̀ mi fún Olúwa,"

ìwọ dárí

̀bi ̀ṣẹ̀ mi . Sela.

6 Nítorí náà jẹ́ gbogbo àwọn olódodo máa gbà àdúrà

ìgbà a ;

nítòótọ́ nígbà ìṣàn omi ńlá ru sókè,

wọn yóò ̀dọ̀ rẹ̀.

Veja também