Pular para o conteúdo
Publicidade

Saamu 34

1 Èmi yóò máa fi ìbùkún fún Olúwa nígbà gbogbo;

ìyìn rẹ̀ yóò máa ẹnu mi títí láé.

2 Ọkàn yóò máa ṣògo nínú Olúwa;

jẹ́ àwọn onírẹ̀lẹ̀ gbọ́ inú wọn ó máa dùn.

3 Gbé Olúwa ga pẹ̀mi;

jẹ́ a jọ gbé orúkọ rẹ̀ lékè.

Estes versículos te tocaram? Ore agora!

+581 estão orando agora.

Junte-se à corrente de oração.

Veja também