Pular para o conteúdo
Publicidade

Saamu 68

3 Ṣùgbọ́n inú olódodo ó dùn

ó kún fún ayọ̀ níwájú Ọlọ́run;

inú wọn ó dùn, ó kún fún ayọ̀.

4 kọrin Ọlọ́run,

kọrin ìyìn i,

la ̀fún ẹni ń rékọjá aginjù.

Olúwa ni orúkọ rẹ̀, máa yọ̀ níwájú rẹ̀.

5 Baba àwọn aláìní baba àti onídàájọ́ àwọn opó ni Ọlọ́run ibùgbé

rẹ̀ mímọ́

Estes versículos te tocaram? Ore agora!

+581 estão orando agora.

Junte-se à corrente de oração.

Veja também