Pular para o conteúdo
Publicidade

Saamu 96

1 96.1-13: 1Ki 16.23-33. kọrin tuntun Olúwa,

kọrin Olúwa gbogbo ayé.

2 kọrin Olúwa, yin orúkọ rẹ̀

sọ ti ìgbàlà rẹ̀ ọjọ́ ọjọ́.

3 sọ ti ògo rẹ̀ láàrín àwọn orílẹ̀-èdè

àti iṣẹ́ ìyanu rẹ̀ láàrín gbogbo ènìyàn.

Estes versículos te tocaram? Ore agora!

+581 estão orando agora.

Junte-se à corrente de oração.

Veja também