Publicidade

Salmos 133

Orin fún ìgòkè. Ti Dafidi.

1 Kíyèsi, ó ti dára ó ti dùn fún

àwọn ará láti máa jùmọ̀ gbé ìrẹ́pọ̀.

2 Ó dàbí òróró ìkunra iyebíye orí,

ó sàn irùngbọ̀n, àní irùngbọ̀n Aaroni:

ó sàn etí aṣọ sórí rẹ̀.

3 ìrì Hermoni

o sàn sórí òkè Sioni.

Nítorí níbẹ̀ Olúwa gbé pàṣẹ ìbùkún,

àní ìyè láéláé.

Veja também

Bíblia Online Bíblia Online

Bíblia Online • Versão: 2026-07-05_12-11-46-