Pular para o conteúdo
Publicidade

Saamu 149

1 fi ìyìn fún Olúwa.

kọrin tuntun Olúwa.

yìn ín àwùjọ àwọn ènìyàn mímọ́.

3 Jẹ́ wọn ó fi ijó yin orúkọ rẹ̀

jẹ́ wọn ó fi ohun èlò orin kọrin ìyìn i.

4 Nítorí Olúwa inú dídùn àwọn ènìyàn rẹ̀

ó fi ìgbàlà àwọn onírẹ̀lẹ̀ ládé.

5 Jẹ́ àwọn ènìyàn mímọ́ ó yọ̀ nínú ọlá rẹ̀

wọn ó máa kọrin fún ayọ̀ orí ibùsùn wọn.

Estes versículos te tocaram? Ore agora!

+581 estão orando agora.

Junte-se à corrente de oração.

Veja também