Pular para o conteúdo
Publicidade

Salmos 30

1 Èmi yóò kókìkí i rẹ, Olúwa,

nítorí ìwọ ni ó gbé mi lékè

ìwọ jẹ́ àwọn ̀mi ó yọ̀ .

2 Olúwa Ọlọ́run mi, èmi ́ fún ìrànlọ́wọ́,

ìwọ ti sàn.

3 Olúwa, ìwọ ti yọ ọkàn mi jáde kúrò nínú isà òkú,

mi padà bọ̀ sípò alààyè èmi ba à lọ sínú ihò.

Veja também