Pular para o conteúdo
Publicidade

Saamu 37

25 Èmi ti ni èwe, báyìí èmi dàgbà;

síbẹ̀ èmi ì ì ri a kọ olódodo sílẹ̀,

tàbí irú-ọmọ rẹ̀ máa ṣagbe oúnjẹ.

26 Aláàánú ni òun nígbà gbogbo a máa ni;

a máa bùsi i fún ni.

Estes versículos te tocaram? Ore agora!

+581 estão orando agora.

Junte-se à corrente de oração.

Veja também